Asòfin Ahmed Lawan di Àarẹ Ilé Asòfin Àgbà

Lawan Emerges as Senate President
June 11, 2019
Monarch Escapes Abduction by Suspected Herdsmen in Ondo
June 12, 2019
Asòfin Ahmed Lawan di Àarẹ Ilé Asòfin Àgbà

Asòfin Ahmed Lawan tó ńsojú àríwá Yobe ni wọ́n ti yàn gẹ́gẹ́bí adarí ile asòfin àgbà báyi.

Asòfin Lawan ní ìbò mọ́kàndínlọ́gọ́rin tí asòfin Ali Ndume tó ńsojú ẹkùn Borno sì ní ìbò méjìdínlọ́gbọ̀n.

Ẹwẹ asòfin Ovie ọmọ Agege tó ńsojú àringbùngbùn Delta ti wọlé gẹ́gẹ́bí igbákejì adarí ilé asòfin àgbà.

Asòfin Ovie ọmọ Agege ní ìbò méjìndínláadọrin tí ẹnikeji rẹ̀ Ike Ikeremadu.

Kemi Ogunkọla/Kemi Akintunde

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *