Amòfin pè fún àkóso tó mú yányán lẹ́ka ìjọba ìbílẹ̀

Àmọ̀rọ̀n Lọ Sọ́dọ̀ Ìjọba Láti Pinwọ Isẹ́
June 14, 2019
Àjọ Àgbáyé Sèlèrí Àtìlẹyìn Lórí Ìlànà Àtúnse Ètò Ìdìbò
June 14, 2019

Wọ́n ti ké sáwọn Gómìnà láti yàgò kúrò nídi mima dá sọ́rọ̀ tóní se pẹ̀lú àwọn ìjọba ìbílẹ̀ lẹ́kùn kóowá wọn, papa jùlọ nídi ìgbésẹ̀ fí fẹ́ máà tukọ̀ àkóso ìjọba ìbílẹ̀ fúnra wọn.

Agbẹjórò kan, ọ̀gbẹ́ni Ibrahim Lawal ló sípayá ọ̀rọ̀ yíì, lákokò tó ńgbé ìdánilẹ́kọ kan kalẹ̀ níbi ìpàdé t’ẹ́gbẹ́ àwọn ìjọba ìbílẹ̀ nílẹ̀ Nàijírìa, ALGON, ẹ̀ka tìpínlẹ̀ Ọyọ sàgbékalẹ̀ láti fi sàmì àyájọ́ June12.

Ó sàlàyé pé, àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ sáaba máà ń mú ọ̀rs àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tó jẹ́ ẹ̀ka ìjọba kẹta bí, ojúse tarawọn léyi tóní kòyẹ kóríbẹ̀ ìdí sìnni yíì tíwọ́n fi máà ń fẹ́ tukọ̀ àkóso àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tó wà nípinlẹ̀ wọn.

Nígbà tón gbé ìdánilẹ̀kọ kan kalẹ̀, alága ẹgbẹ́ àwọn oníròyìn, ọ̀gbẹ́ni Adewumi Faniran tọ́kasí pé, ọ̀kan òjọ̀kan nkan la ilé-isẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti akọ̀ròyìn ńpàdánù lákokò rògbòdìnyàn ètò ìdìbì àkókò June12.

Ó sọ síwájú pé, óyẹ káwọn oníròyìn máà ridájú pé, àwọn kò jẹ́ kí ǹkankan sọnù nínú ìròyìn tíwọ́n bá ńgbé lai gbọdọ figbákan bukan nínú lẹ́nusẹ́ tíwanyàn láayo.

Kemi Ogunkọla/Lilian Ibomor

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *