Ìpínlẹ̀ Ọyọ korò ojú sí dídalẹ̀ síbi tí ò yẹ

Àjọ Àgbáyé Sèlèrí Àtìlẹyìn Lórí Ìlànà Àtúnse Ètò Ìdìbò
June 14, 2019
SWAN Members will Get Their Travel Documents with Ease – NIS Comptroller
June 14, 2019
Ìpínlẹ̀ Ọyọ korò ojú sí dídalẹ̀ síbi tí ò yẹ

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọyọ, Onímọ̀ẹ̀rọ Seyi Makinde ti pàsẹ kí òpin débá dída àti gbígbé ilẹ̀ sáàrin méjì òpópóonà àti àwọn ibi tí ò tọ miràn.

Eléyi jẹyọ níbi àtẹ̀jáde tí Gómìnà fi síta láti ipasẹ̀ akọ̀wé ìròyìn Taiwo Adisa.

Gómìnà koro ojú sí àsà dídalẹ̀ sí ibi tí ó gẹ́ tó ńwáyé kákiri ìpínlẹ̀ Ọyọ tó sì ní kí gbogbo olùgbé ìpínlẹ̀ Ọyọ máà se àmúlò goro ìdalẹ̀nùsí kí wọ́n sì forúkọ sílẹ̀ pẹ́lú àwọn iléesẹ́ kólẹ̀ kódọ̀tí tó bá fún agbègbè wọn fún kíkó àwọn ìdọ̀tí.

Gómìnà sọ síwájú pé, dídalẹ̀ sójú àgbàrá ló máà ńsokun fa ẹ̀kún omi tó sì fikún pé, ìjọba kò ní tẹ̀tì láti fojú ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sí òfin yi winà òfin.

Kemi Ogunkọla/PR

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *