Iléesẹ́ ọlapa sàmúlò ajá gẹ́gẹ́bí irinsẹ́ ètò àbò

Àwọn àgbẹ̀ bèèrè ìránlọ́wọ́ ìjọba lórí ọ̀gbìn Jathropha
June 26, 2019
Expert Urges Farmers to Utilize Potential of Jathropha Seed
June 26, 2019
Iléesẹ́ ọlapa sàmúlò ajá gẹ́gẹ́bí irinsẹ́ ètò àbò

Iléesẹ́ ọlapa nílẹ̀ yí ti bẹ̀rẹ̀ sini sàmúlò ajá gẹ́gẹ́bí irinsẹ́ láti mú kágbega bá ọ̀rọ̀ ètò àbò nílẹ̀ yí.

Alákoso fún olúlu ilésẹ́ ọlọ́pa, Owowe Aishatu Abubakar ló sọ̀rọ̀ yi lásìkò tó ń kópa lórí ètò ilésẹ́ Radio Nigeria àpapọ̀ kan.

Ọmọwe Abubakar sàlàyé pé, àwọn ọlọ́pa ti kọ́ àwọn ajá tí wọ́n ń sàmúlò lọ́nà àti mọ ẹni tó ń gbé ògùn olóró tófimọ́ àwọn ǹkan ìjà ogun èyí tí erọ lé ma tètè kẹ́fín.

Ọmọwe Abubakar sọ pé pàtàkì sísàmúlò àwọn ajá ní láti fi mú àdínkù ba gbígbé ògùn olóró, ó wá rọ àwọn èyàn àwùjọ láti sísẹ papọ̀ pẹ̀lú ilésẹ́ alábo láti mú kíwà ọ̀daràn di oun ìgbàgbé lórólẹ̀èdè yí.

Kẹmi Ogunkọla/Ayọade

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *