Ogagba tuntun fun NNPC jeje láti ṣe atunto àjọ òhun

Police Reintroduces Sporting Activities
July 11, 2019
Ilé ìgbìmò asofin ìpínlè Ọ̀yọ́ fofin gbe ituka àjọ eleto ìdibo
July 11, 2019
Ogagba tuntun fun NNPC jeje láti ṣe atunto àjọ òhun

Ogagba tuntun èyí tí jọba ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn sípò lajo tó ń rísí epo ròbi nílè yi NNPC, Ogbeni Mele Kyari ti jeje láti ṣe atunto àjọ òhun.

Ó sọ pé òun yo ri dájú pé àjọ NNPC, lè ṣe kangbọn pẹ̀lú irúfé àjọ yi lagbaye.

Ogbeni Kyari jeje yi lásìkò tó se àgbéyèwò, ekuse nbeun sí akọ̀wé ìjọba Àpapọ̀, Ogbeni Boss Mustapha lofisi rẹ pẹ̀lú ẹni tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gbase lọ́wọ́ rè, Ogbeni Maikati Barru, tí wọ́n sì fi ẹ̀mí imore hàn fún iyansupo lélẹ̀ kejì, Ogbeni Mustapha gẹ́gẹ́bí akọ̀wé ìjọba Àpapọ̀.

Ogagba tuntun fajo NNPC, tún sọ̀rọ̀ ìdánilójú pé atunto atamugboro yọ ba àwọn ibùdó ifopo nílèyí, lónà àti ri dájú pé epo yo má wà fún lilo lorekore.

Nígbà tó ń fèsì, Ogbeni Mustapha fi dá ogagba tuntun NNPC, lójú pé ibasepo tó loorin yowa láti mú ètò isejoba ọdún mẹ́rin tó ń bo lọ, laisi rògbòdìyàn kankan.

Kemi Ogunkola/Kehinde

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *