Onímọ̀ gba ìjọba nímọ̀ràn lórí ètò ààbò

UI: NASU, SSANU Protest Continues
July 17, 2019
Checking the Menace of Indiscriminate Siting of Gas Sales Outlets
July 17, 2019
Onímọ̀ gba ìjọba nímọ̀ràn lórí ètò ààbò

Àmọ̀ràn ti lọ sọ́dọ̀ ìjọba àpapọ̀ láti mú ètò àabò ní baada pẹ̀lú gbogbo àwọn ìpèníjà tó ńkojú ilẹ̀ wa lórí ètò àabò.

Olùkóni kan láti ẹ̀ka tí wọ́n ti ńkọ́ nípa ọ̀rọ̀ òsèlú nílé ẹ̀kọ́ fásitì kan, ọ̀mọ̀wé Moses Duruji tó sọ̀rọ̀ àmọ̀ràn yi nígbà tó ńba akọ̀ròyìn wa sọ̀rọ̀.

Ó sọ síwájú pé, ìwé àpilẹ̀kọ tí olórí ilẹ̀ wa tẹ́lẹ̀rí fi sọwọ́ sí àarẹ Buhari jẹ́ èyí tó bọ́ sásìkò pẹ̀lú àfihàn pe ó yẹ kí ìfikùnlukùn máà wáyé lóórekoore láàrin àwọn tétò ààbbò kan kí ojútu lè wáyé si gbogbo kùdiẹ kudiẹ àti àkùdé tó ńbá ilẹ̀ Nàijírìa fínra.

Ọmọwe Duriji wá rawọ́ ẹ̀bẹ̀sí Àarẹ Buhari láti mú kírètí àwọn ọmọ ilẹ̀ yi má jọba.

Kémi Ogunkọla/Ayọade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *