Ifehonuhan: Alase Fasiti Oye Ekiti Sagbekale Iko Eleni Mejila

Clergy Tasks Nigerians on Exemplary Lifestyle
September 13, 2019
PDP Ekun Iwo Orun Gusu Fowosi Ejo Kotemilorun
September 13, 2019
Ifehonuhan: Alase Fasiti Oye Ekiti Sagbekale Iko Eleni Mejila

Giwa  Fasiti Oye Ekiti, Ojogbon Kayode Soremekun, tise agbekale iko eleni mejila kan latise iwadi lesekese lori on to sokunfa ifehonuhan ojo isegun tokoja ati ikolu aya Gomina Ipinle Ekiti, Erelu Fayemi, ati bi awon meji se padanu emi won ninu ikolu naa.

Ninu atejade eyi ti Ojogbon Soremekun fowosi nilu Oye Ekiti ni oro naa ti jade, pelu alaye pe igbese  naa yoo gena irufe rogbodiyan naa lojowaju.

Bakanna lotun benu ate lu isele naa, to si seleri lati mu atunto ba ilana ile eko giga Fasiti naa. Igbimo eleni mejila naa ti yoo se iwadi naa ni Igbakeji ile eko naa, Ojogbon AbayomiFashina je alaga fun, ti Arabinrin Blessing EyiOlorunfe si je Akowe.

Ogunkola/Ogunrinde

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *