PDP Ekun Iwo Orun Gusu Fowosi Ejo Kotemilorun

Ifehonuhan: Alase Fasiti Oye Ekiti Sagbekale Iko Eleni Mejila
September 13, 2019
Police Parades Suspected Rapists, Murderers in Ibadan
September 13, 2019
PDP Ekun Iwo Orun Gusu Fowosi Ejo Kotemilorun

Egbe Oselu Peoples Democratic Party, PDP, ekun iwo orun gusu, ti sope awon yoo satileyin fun egbe naa lati pe ejo kotemilorun lori idajo eyi ti igbimo ton gbo awuye wuye lori ibo aare gbe kale.

Oro yi je jade ninu atejade eyi ti igbakeji agbarijopo alaga egbe oselu PDP lekun naa, Omowe Eddy Olafeso fowosi lehin ipade to waye nilu Ibadan.

Atejade naa fi aidunu won han lori idajo naa, ti won si sope ile ejo ko gbe idajo naa le gbogbo eri to wa niwaju igbimo naa.

Saaju ni Gomina Ipinle Oyo, Onimo Ero Seyi Makinde pe fun isokan laarin egbe PDP lekun iwo orun gusu ati ile naijiria lapapo, kegbe naa le laseyori, ki won si bori ipenija to wa niwaju won.

Ogunkola/Adebisi

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *