Yoruba

February 18, 2019

Ẹgbẹ Akẹ́kọ sè Ìlérí fáwọn Olósèlú lórí Ìtàjẹ̀sílẹ̀

Ẹgbẹ àwọn akẹ́kọ lórílẹ̀èdè Nàijírìa, NANS, ti pàrọwà sí àwọn olósèlú pé kí wọ́n máse tàjẹ̀ sílẹ̀ ní bí wọn […]
February 16, 2019

Onidajo Agba laago ikilo fawon adajo

Adele Adajo Agba ile yii, Onidajo Tanko Muhammed ti laago ikilo seti awon adajo ti yoo seto ejo to ba […]
February 16, 2019

Idibo: Amoran lo sodo omo ile Naijiria latodo MMPN

Didibo fun olori ti yoo soju wa gbodo je ohun to mumulaya gbogbo omo ile yii. Eleyi jeyo ninu atejade […]
February 14, 2019

Àjọ elétò ìdìbò fi aráalu lọ́kàn balẹ̀ lórí ìdìbò

Àjọ elétò ìdìbò ilẹ̀ yíì,INEC, sọpé mìmì kankan kòní mì ètò ìdìbò sí ipò Àarẹ láifi ti iná ọmọ rara […]
February 13, 2019

Àjọ tó ńbójútó iléésẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ laago ìkìlọ̀ lórí ìdìbò tó ńbọ̀

Wọ́n ti kílọ̀ fáwọn iléesẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti àwọn olósèlú nípínlẹ̀ Ọyọ láti máse si iléésẹ́ ìròyìn lò gẹ́gẹ́bí àjọ tó […]
February 13, 2019

Àmọ̀ràn lọ sọ́dọ̀ àwọn ọ̀dọ́ láti yàgò fún jàgìdìjàgan

Wọ́n ti kìlo fáwọn sdọ́ láti máse jẹ́kí wọ́n ó lò wọ́n fún irinsẹ́ ìdàlúrú lásìkò òdìbò. Olùdásílẹ̀ ìjọ Shafaudeen […]
February 11, 2019

Ìpínlẹ̀ Ọyọ ní ọ̀gá ọlọ́pa tuntun

Ọga ọlọ́pa tuntun tí yo ma sàkóso iléésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ Ọyọ, ti bẹ̀rẹ̀ isẹ́ lẹ́yìn tí wọ́n gbé ẹni tó […]
February 11, 2019

Gbèdéke gbígba káádi ìdìbò wá sópin

Òní ni ètò gbígba káadi ìdìbò PVC, yo wa sópin. Alága àjọ elétò ìdìbò lórílẹ̀èdè yi, INEC, ọ̀jọ̀gbọ́n Mahmood Yakub […]
February 11, 2019

Iléésẹ́ ọlọ́pa sèlérí, àabò tó péye lásìkò ìbò

Adalé ọ̀gá ọlọ́pa yányán lórílẹ́èdè yi, ọ̀gbẹ́ni Mohamed Adamu, ti pàsẹ pé, kí ètò ààbò le dain-dain ní gbogbo ọ́ọ́fìsì […]