íjọba Àpapọ̀

February 10, 2019

Ijọba Apapọ fi Araalu Lọkan Balẹ Lori Aabo Lọjọ Idibo

Olubadamọran Agba lori ọrọ aabo nilẹ yii, Mohammed Monguno ti fi awọn ọmọ ilẹ yii lọkan balẹ pe ko ni […]
January 24, 2019

Ijọba Apapo ngbero afikun idiyele ori oja.

Ijọba Apapọ ngba lero lati fikun idiyele ori oja,fun odun 2019 tawayi. Alakoso fọrọ etọ isuna Arabinrin Zainab Ahmed lo […]
January 17, 2019

Ìjọba Àpapọ̀ yo gbe àbá sísan owó osù tuntun síwájú NEC

Lọ́la ni ìjọba àpapọ̀ yo gbe àbá sísan ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n naira gẹ́gẹ́bí owó osù tó kéréjùlọ síwájú NEC. Àjọ […]
January 3, 2019

Ìjọba àpapọ̀, ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga fásitì yóò se ìpàdé papọ̀

Bákannà, Ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀èdè yíì àtẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ láwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga fásitì, Assu, ti setán láti sọ̀rọ̀ lórí ìyansẹ́lódì àwọn […]
December 4, 2018

Ìjọba Àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ akin lórí ríra ohun ìjà ogun

Ilé isẹ́ àarẹ ti pàsẹ pé kí àwọn ohun èèlò ìjagun máà jẹ́ rírà látọ̀dọ̀ àwọn tó ńrọ wọ́n ní […]
September 17, 2018

Ìjọba àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ láti mú àgbéga bá ẹ̀ka Ìlera

Gẹ́gẹ́bí ara akitiyan ìjọba àpapọ̀ láti mú kí ìpèsè ètò ìlera aláabọ́dé túbọ̀ gbé pẹ́ẹ́lí si, àarẹ Muhamadu Buhari yo […]
September 3, 2018

Ìjọba àpapọ̀ rọ àwọn ìjọba Ìpínlẹ̀ lati wójùtú sí ìpèníjà ètò àbò

Ìjọba àpapọ̀ ti rọ ìjọba ní Ìpínlẹ̀ mẹ́fẹ̀fàlélọ́gọ́ta rẹ̀ tófimọ́ olú-ìlú ilẹ̀ wa Abuja, láti sétò ìgbésẹ̀ tóóyẹ tí yóò […]
August 3, 2018

Ìjọba àpapọ̀ gbégbesẹ̀ lórí àgbéga iná ọba

Yorùbá bọ̀ wọ́n ní ẹni tó bá lè gbani láà fọ̀rọ̀ọ̀lọ̀, gẹ́gẹ́ ara ìgbìnyànjú rẹ̀ láti mágbega ìpèsè iná ọba […]
July 18, 2018

Ìjọba Àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ lórí àmúgbòorò okòòwò

Kònípẹ́ táarẹ orílẹ̀dè yíì Muhammọdu Buhari yóò fi sí sọ lójú ètò kan láwọn ibùdókọ̀ ojúomi, pápákọ̀ òfurúfú àtàwọn ẹnubòdè […]