ípinlẹ Ògùn

February 10, 2019

Ipolongo ibo Aare Buhari: Eto abo buyari si ni ipinle Ogun

Eto abo ti buyari si bayii loluulu ipinle Ogun nigbaradi feto ipolongo ibo egbe oselu All Progressive Congress, APC. Gege […]
December 25, 2018

Amosun Yo Pelu Awon Eeyan Ipinle Ogun L’ajoyo Odun Keresimesi

Gomina Ibikunle Amosun ti ipinle Ogun nfe ki awon kristeni ko gbe emi ife ati ipamora wo ki alaafia ba […]
July 16, 2018

Ìpínlẹ̀ Ògùn sèlérí líla ojútó omi láti dènà ẹ̀kún omi

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn ti sèlérí láti gùnlé ìgbésẹ̀ líla ojúnà tí omi yóò máà gbà sàn gẹẹrẹgẹ láti dènà ìsẹ̀lẹ̀ […]
June 8, 2018

Iléésẹ́ Ológun sèlérí ààbò tó gbópọn fáwọn olùgbé Ìpínlẹ̀ Ògùn

Ilé-isẹ́ ológun ilẹ̀ yíì sọ pé, digbí lòun síwa láti pèsè ètò àbò tó múná dóko fáwọn olùgbó Ìpínlẹ̀ Ògùn. […]
January 18, 2018

Ìpínlẹ̀ Ògùn gbésẹ̀ láti fòpin sí kíkó ẹrù tí o bófinmu wọ̀lú

Lára akintiyan rẹ̀ láti mádínkù bá kíkó àwọn ohun tí o bófinmu nípínlẹ̀ Ògùn, ìjọba ìpínlẹ̀ náà ti sèlérí láti […]
October 26, 2017

Ìjọba àpapọ̀ fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ìpínlẹ̀ ògùn láti sàgbéga Àsà

Ìjọba àpapọ̀ tí setán láti sàtìlẹyìn fún ìpínlẹ̀ ògùn nídi akitiyan láti sọ orírun mọ̀lẹ́bí Ransome Kuti tó wà nílu […]
September 26, 2017

Ìpínlẹ̀ Ògùn tí nawọ́ ìbásepọ̀ sí ilẹ̀ Benin lórí isẹ́ àgbẹ̀

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn tí nawọ́ ìbásepọ̀ sí ilẹ̀ Benin ní ẹ̀bá isẹ́ àgbẹ̀, àti isẹ́ ọwọ́ fún ìdàgbàsókè ọrọ̀ ajéÌpínlẹ̀ […]
August 7, 2017

Ìpínlẹ̀ Ògùn gbe ìgbésẹ̀ akin láti dẹ́kun ayédèrú Òogùn

Nídi àti jáwe dẹ́un fún kíkó wọlé ayédèrú òogùn òyìnbó npílẹ̀ Ògùn, Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn tí se àgbékalẹ̀ ìgbìmọ̀ kan […]
June 7, 2017

Ámósùn, gbà wá lọ́wọ́ ẹ̀kún omi – Ará ìlú

Àwọn ará agbègbè máárun láti ìjọba ìbílẹ̀ Adó odò ọtà nípinlẹ ògùn tí ké gbàjarì sí ìjọba láti wa gba […]