ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọsìnbájo

May 15, 2019

Igbakeji Aare Sekilo lori Ajebanu

Igbakeji Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo ti sekilo fawon eeyan lati dehin nidi fifun awon osise ijoba lowo abetele tiwon ba […]
August 8, 2018

Akọ̀wé tẹ́lẹ̀ fun jọba àpapọ̀ gbóríyìn fádelé Ààrẹ

Akọ̀wé tẹ́lẹ̀ síjọba àpapọ̀ orílẹ̀dè yíì, Olóyè Olu Falae ti sàpèjúwe ìgbésẹ̀ bíwọ́n se ní kí olùdarí àgbà pátápátá fẹ́ka […]
May 23, 2018

Ìjọba Àpapọ̀ bẹnu àtẹ́ lu ìsẹ̀lẹ̀ ìsekúpani

Igbákejì Àarẹ orílẹ̀dè yíì, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo ti bẹnuàtẹ́lu bí ìsẹ̀lẹ̀ ìsekúpani láwọn ilé-ìjọsìn se ńgogò si láwọn apá ibìkan […]
May 16, 2018

Ìjọba Àpapọ̀ sọ Àfojúsùn rẹ̀ lórí ètò ìràpadà ọrọ̀ Ajé

Igbákejì Àarẹ ilẹ̀ yíì, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Osinbajo so pé ètò tíjọba gbékalẹ̀ fún ìràpadà ètò ọrọ̀ ajé àtìdàgbàsókè, ERGP, ló […]
April 6, 2018

Ìjọba Àpapọ̀ Fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Aládani lórí ọrọ̀ ajé

Igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ yíì, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo sọ pé, Ìjọba Àpapọ̀ orílẹ̀dè yíì setán, látiridájú pé òun tọ́wọ́ àwọn ẹ̀ka […]
February 14, 2018

Àwọn Gómìnà àti ọmọ ilé asòfin fọnrere ìdásílẹ̀ ọlọ́pa ìpínlẹ̀

Àwọn Gómìnà àti àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asòfin ti sàdéhùn láti fààyé gba ìdásílẹ̀ ọlapa ìpínlẹ̀. Èyí jẹ́ ọ̀kan lára […]
August 29, 2017

Àarẹ Buhari: Ẹkọ láti máà ní ìfaradà àti ìfẹ́ síraẹni

Lọ́jọ́ kọkàndínlọ́gbọn osù karun ọdún 2015, niwọ́n búra fáàrẹ Muhammodu Buhari bọsípò àkóso pẹ̀lú èróngbà láti máyipadà rere ba ilẹ̀ […]
June 14, 2017

Àwọn Aráálu sọ́rọ nípa Àmúlò ètò ìsúná ọdún 2017

Ìsọ̀rí àwọn ènìyàn kán ní ìlú ìbàdàn tójẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ n fẹ́ kí ìjọba na owó ìsúná tíwọ́n […]